Oruko Jesu

K’aiye to ta oruko Jesu, on dara fun wa
K’aiye to dale oruko Jesu, on dara fun wa
Eda yara pada sodo Jesu, ko dara fun o
K’aiye to ta oruko Jesu, on dara fun wa
K’aiye to dale oruko Jes, on dara fun wa
Eda yara pada sodo Jesu, ko le dara fun o

Omo gbo ohun Oluwa ɾe ke tan tan si o oo, omo gbo

Ko ma si, eni to [C7]le gba o ninu iji aiye , ko ma si

K’aiye to [C7]ta oruko Jesu, on [C7]dara fun wa
K’aiye to [C7]dale oruko Jesu, on [C7]dara fun wa
Eda yara pada sodo Jesu, ko dara fun o
K’aiye to [C7]ta oruko Jesu, on [C7]dara fun wa
K’aiye to [C7]dale oruko Jesu, on [C7]dara fun wa
Eda yara pada sodo Jesu, ko le dara fun o
Eda yara pada sodo Jesu, ko le dara fun o
Eni to [C7]gba wa la lowo iku oro, bee ni
O ja wa gba lowo egun ta bi wa si, bee ni
Owo to [C7]mo wa ko ni s’alai le gba wa, ɾa ɾa o
Eni to [C7]da eti koni s’alai gboron, bee ni
K’aiye to [C7]ta oruko Jesu, on [C7]dara fun wa
K’aiye to [C7]dale oruko Jesu, on [C7]dara fun wa
Eda yara pada sodo Jesu, ko le dara fun o
Eda yara pada sodo Jesu, ko le dara fun o
Aiye sare leje leje
Eniyan bu ɾin o f’ese ko ku
Awon [C7]ta mu latori aatan ta wa fi j'oba
Isoro de won [C7]sare eru won [C7]ti gba gbe [Am]eni to [C7]gba wa o
Ko ni s’alai gbawa tan won [C7]sare iku
Eda ɾo ju tan, on [C7]wa airoju o to [C7]ju su ni o, ee see
Eni to [C7]ni ala olumuse ala oruko ɾe ni ala nla
Ese je je isoro de b’olorun soro mata Jesu, ofe la fun o
Odale pada ko ma ba bale lo
Oluta ofe igbala da owo won [C7]pada fun won
Ranti judasi ta ofe o pada pokun so
Eda yara pada sodo Oluwa ɾe ko le dara fun o
K’aiye to [C7]ta oruko Jesu, on [C7]dara fun wa
K’aiye to [C7]dale oruko Jesu, on [C7]dara fun wa
Eda yara pada sodo Jesu, ko le dara fun o
Eda yara pada sodo Jesu, ko le dara fun o
Log in or signup to leave a comment

NEXT ARTICLE