Hm mm Baba mi Eledumare
Hmm mmm
Iwo ni Olorun mi
Mo juba re
(Iwo nii) Iwo ni Olorun mi
(Kabiyesi re) Kabiyesi
(Iwo l’Oba) Iwo ni Olorun mi
(Mo ma juba re) Mo juba re
(Iwo ni, iwo ni) Iwo ni Olorun mi
(Kabiyesi re) Kabiyesi (Hmmmm)
Mo yin o aaa
Ologo ju lo, oloruko nla
Sin sin le mi o ma sin o titi aiye mi o
(Iwo ni) Iwo ni Olorun mi
(Mo ma juba ɾe) Mo juba ɾe
(Iwo ni oba, iwo ni oba) Iwo ni Olorun mi
(Kabiyesi o) Kabiyesi
Bi iya ati baba ba ko mi sile
Oluwa yio tewo gba mi
When my [A]father and [Bm]my [A]mother forsake me
The lord will ɾeceive me
(Iwo l’Oba) Iwo ni Olorun mi
(Mo juba ɾe) Mo juba ɾe
(Alagbada ina, alawotele orun) Iwo ni olorun mi
(Iwo ni kan so so, kan sho oo) Kabiyesi
(Oba tin f’oba je iwo l’Oba) Iwo ni olorun mi
(Olorun mi, Eledumare) Mo juba ɾe
(Mo juba ɾe) Iwo ni Olorun mi
(Iwo ni Olorun mi) Kabiyesi
Mo gbe [Am]ke le iwo nikan o Oluwa mi
Iwo ni Olorun mi
N’je ti ɾe titi lai ati lai lai
Olufe okan mi
(Olorun mi eee) Iwo ni Olorun mi
(You are my [A]God forevermore) Mo juba ɾe
(And I will worship you [A7for [Dm7]the ɾest of my [A]life) Iwo ni Olorun mi
(Iwo lo’lorun mi ooo, Kabiomasi) Kabiyesi
Ranti ojo yen to [C7]gba nkan to [C7]bere
Ranti bi Olorun se pese fun o
Ranti bi Olorun se gba o la lowo aiye
Ranti b’o se s’ope lojo yen
Ranti b’o se jo
Ranti idunu ayo ɾe
Ma gbagbe [Am]o
Because when things get tough, you [A7are still expected to [C7]praise him the same -
B’orun ba n’ran, t’iji ba nja, o si ye ko yin Oluwa l’ogo
Yin, ko si gbe [Am]oruko ɾe ga
Ohun ni oba ton [C7]se ohun gbogbo ni akoko tio to
Aseyi owu ni orun ati ni aiye
Ni okun ati ni ogbun gbobo
Alakoso gbogbo emi eniyan
Ibere ati opin
(Kabiomasi o)
(Iwo ni Olorun mi) Iwo ni Olorun mi
(Olugbala Olorun olutoju aiye wa) Mo juba ɾe
(Adani ma gba gbe [Am]eni, owi be [Am]se be) Iwo ni Olorun mi
(Olorun asoromaye) Kabiyesi
(Kabiomasi ooo)
Iwo ni Olorun mi
Mo juba ɾe
Iwo ni Olorun mi
Kabiyesi