Baba Orun

Great and mighty King
Glorious and wonderful
All things are made perfect in your holy name
Baba orun e
Baba orun Eledua Eledua
Baba orun Eledua mo se ba re
Baba orun Eledua mo se ba re
Baba orun Eledua mo se ba re
Baba orun Eledua mo se ba ɾe
Ope ni fun Oluwa
Iyin lo ye Jesu baba ti wa
Ope ni fun Oluwa
You deserve all [Em]the glory
You deserve all [Em]the honour Jesus
Moriba moriba Baba mi Oba nla tin f’oba je
Moriba moriba Baba mi Oba nla tin f’oba je
Moriba moriba Baba mi Oba nla tin f’oba je
Moriba moriba moriba Baba mi Oba nla tin f’oba je
Ogo ni f’oruko ɾe mo yin o logo
Ari ɾo ala mo se ba fun o
Gbani gbani t’aiye saya ajuba ɾe Olorun akoda aiye
Gbani gbani t’aiye saya ajuba ɾe Olorun akoda aiye
(Baba Orun) Gbani gbani t’aiye saya ajuba ɾe Olorun akoda aiye
(Baba Orun) Gbani gbani t’aiye saya ajuba ɾe Olorun akoda aiye
Baba orun Eledua mo se ba ɾe
Baba orun o Eledua mo se ba ɾe
Baba orun o oo Eledua mo se ba ɾe
Baba orun Eledua mo se ba ɾe
Ogbamu gbamu oju orun o se gbamu
Olowogbogboro Kabiyesi iba ɾe
Opo to [C7]so aiye ɾo baba mi
Ooo iba o
Ogbamu gbamu oju orun o se gbamu
Olowogbogboro Kabiyesi iba ɾe
Opo to [C7]so aiye ɾo baba mi
You deserve all [Em]the glory
You deserve all [Em]the honour Jesus
Moriba moriba Baba mi Oba nla tin f’oba je
Moriba moriba Baba mi Oba nla tin f’oba je
Moriba moriba Baba mi Oba nla tin f’oba je
Moriba moriba moriba e Baba mi Oba nla tin f’oba je
Ogo ni f’oruko ɾe mo yin o logo
Ari ɾo ala mo se ba fun o
Gbani gbani t’aiye saya ajuba ɾe Olorun akoda aiye
Gbani gbani t’aiye saya ajuba ɾe Olorun akoda aiye
(Iku gbo oruko ɾe o wo gbo, arun gbo oruko ɾe o sa wole)
Gbani gbani t’aiye saya ajuba ɾe Olorun akoda aiye
(Alapanla to [C7]sole aiye ɾo, Ogo lo ye o oo) Gbani gbani t’aiye saya ajuba ɾe Olorun akoda aiye
(Ogo lo ye o oo)
(Baba Orun) Eledua mo se ba ɾe
(Baba Orun) Eledua mo se ba ɾe
(Oba mimo, ton [C7]wo mimo, ton [C7]se mimo) Eledua mo se ba ɾe
(Ton [C7]je mimo, Emi mimo) Eledua mo se ba ɾe
(Mimo mimo l'oruko ɾe) Eledua mo se ba ɾe
Eledua (King of king Lord of lords) Eledua
(Mo se ba ɾe)
Log in or signup to leave a comment

NEXT ARTICLE