The Anthem

Sebotimo Sebotimo Sebotimo o
Ani Sebotimo Sebotimo Sebotimo
Alaye ma pokunso
Wo alaye a saye e
Bi igi ba da ninu igbo
Agbo eleye a saye eh
Mase gbo ti won o
Toba lo woa pe alagbo
Won a tun polorin

Ani Sebotimo Sebotimo Sebotimo O
Ani Sebotimo Sebotimo Sebotimo O

Let them [A]go if they say they won [C7]g
Some will wait
Na them [A]fit show you [A7tɾue love
Those wey love you
Hold them [A]tight o
When yawa gas
Na them [A]fit fight o
Oh oh
Ba gun iyan ninu ewe ba sebe [Am]Lepo epa
Oh oh
Ani ma yo ma yo
Ani ma yo ma yo
Firigbon [C7]o silekun
Eni to [C7]ni kokoro lohun si
Oro yi ko gbagidi
Firigbon [C7]o silekun
Eni to [C7]ni kokoro lohun si
Oro yi ko gbagidi
Firigbon [C7]o silekun
Eni to [C7]ni kokoro lohun si
Oro yi ko gbagidi
Firigbon [C7]o silekun
Eni to [C7]ni kokoro lohun si
Oro yi ko gbagidi

Ani Sebotimo Sebotimo Sebotimo O
Sebotimo Sebotimo Sebotimo o
Ani Sebotimo Sebotimo Sebotimo O
Sebotimo Sebotimo Sebotimo o

Bi oni o fe ma sebi
Iwo shama tesiwaju oh oh
Bi o ni o fe ma sere
Iwo shama tesiwaju oh oh
Ayo mbo foninu ire
Pasan tafi nan iyale mbe [Am]Lori Aja
Ayo mbo foninu ire
Pasan tafi nan iyale mbe [Am]Lori Aja
Akisa ti lo igba ɾi o
504 ti lo igba ɾi o
Shebi Olowo oloro nlo 504 nigbayen
Baby Benz ti lo igba ɾi

Ani Sebotimo Sebotimo Sebotimo O
Ore Sebotimo Sebotimo Sebotimo O
Ani Sebotimo Sebotimo Sebotimo O
Oga ile ise Sebotimo Sebotimo Sebotimo o
Đăng nhập hoặc đăng ký để bình luận

ĐỌC TIẾP