Soapy

Ó t'esè'lé bò
Yahoo ni babaláwo (Yahoo ni babaláwo)
Olè l'everybody
Eni ilè mó bá ṣá ni bàráwò
(Bàráwò, bàráwò, bàráwò)
Mó bá ṣá ni bàráwò

Ó t'esè'lé bò (Ó t'esè'lé bò)
Yahoo ni babaláwo (Yahoo ni babaláwo)
Olè l'everybody
Eni ilè mó bá ṣá ni bàráwò
Ó fé ṣè'kà fún mi (Ófé ṣè'kà fún mi)
Mi ò l'ógùn mo ní Kùránì (Mo ní Kùránì)
Mo dè ń ṣ'àdúrà mi
Bí n sé ń ṣ'àdúrà mi, Allah ń gbà'dúrà mi (Allah ń gbà'dúrà mi)
A ti lo a ti dé (A ti lo a ti dé)
Eni orí yo ó dilé (Eni orí yo ó dilé)
Ení ba lo l'ó ba dé
Ìgbà tí n padà dé ń'ṣe l'ón dé mi l'ádé (Ń'ṣe l'ón dé mi l'ádé)
K'ádé k'ó pé l'órí (K'ádé k'ó pé l'órí)
Kí bàtà k'ó pé l'ésè (Kí bàtà k'ó pé l'ésè)
K'àwon [C7]òtá mi kán l'ésè
K'àwon [C7][?] kí wón kán l'ésè

Inside life, l'oó ti ɾí Five Alive (L'oó ti ɾí Five Alive)
Inside life, l'oó ti ɾí Deeper Life (L'oó ti ɾí Deeper Life)
Inside life àwon [C7]kan ń jè'yà, àwon [C7]kan ń chop life (Inside life)
Inside life àwon [C7]kan ń ṣ'épè, àwon [C7]kan ń j'èwà

Jó soapy (Soapy)
Kiríkirì ń jó soapy (Kiríkirì ń jó soapy)
Jó soapy (Soapy)
Ìkòyí prison [C7]ń jó soapy (Ìkòyí prison [C7]ń jó soapy)
Jó soapy
Nínú cell EFCC wón ń jó soapy (Wón ń jó soapy)
Jó soapy
T'ó ò bá ní'yàwó ń'lé k'o jó soapy (Soapy)
Soapy (Soapy)
Bròdá yì ń jó soapy (Bròdá yì ń jó soapy)
Soapy (Soapy)
Àbí èyin náà soapy (Àbí èyin náà soapy)
Soapy (Soapy)
Single father ń jó soapy (Single father ń jó soapy)
Soapy
Má lo lo Omo t'o bá lo ń soapy (Soapy)

Ṣ'o d'ówó mò (Ṣ'o d'ówó mò)
Owá so pé òmo Naira (Owá so pé òmo Naira)
Ówúwo l'ówó, ìwo ṣáà ṣe sí Naira (Ìwo ṣáà ṣe sí Naira)
Ajá fé dè'nà d'ekùn
Kékeré ekùn ò mà ń ṣ'egbé ajá (Kò ń s'egbé ajá)
Wón ń bé ni, má fòó, àwon [C7]náà ò fé wàhálà (Àwon [C7]náà ò fé wàhálà)
I just want make mama proud (I just want make mama proud)
They want to [C7]make mama cry (They want to [C7]make mama cry)
Mama, you [A7gonna cry no more
T'e bá sun'kún gan, e ó so'kún ayò (E ó so'kún ayò)
Tí n bá ń jó k'e bá n yò (K'e bá n yò)
K'órò mí já s'áyò (K'órò mí já s'áyò)
Inside life (Inside life)
Kú àwon [C7]'cause it's my [A]life (Kú'òn'bè!)

Inside life, l'oó ti ɾí Five Alive (L'oó ti ɾí Five Alive)
Inside life, l'oó ti ɾí Deeper Life (L'oó ti ɾí Deeper Life)
Inside life àwon [C7]kan ń jè'yà, àwon [C7]kan ń chop life (Inside life)
Inside life àwon [C7]kan ń ṣ'épè, àwon [C7]kan ń j'èwà

Jó soapy (Soapy)
Kiríkirì ń jó soapy (Kiríkirì ń jó soapy)
Jó soapy (Soapy)
Ìkòyí prison [C7]ń jó soapy (Ìkòyí prison [C7]ń jó soapy)
Jó soapy
Nínú cell EFCC wón ń jó soapy (Wón ń jó soapy)
Jó soapy
T'ó ò bá ní'yàwó ń'lé k'o jó soapy (Soapy)
Soapy (Soapy)
Bròdá yì ń jó soapy (Bròdá yì ń jó soapy)
Soapy (Soapy)
Àbí èyin náà soapy (Àbí èyin náà soapy)
Soapy (Soapy)
Single father ń jó soapy (Single father ń jó soapy)
Soapy
Má lo lo Omo t'o bá lo ń soapy (Soapy)
Log in or signup to leave a comment

NEXT ARTICLE