Ogologo

Marley naira
Pounds oun segbe dollar
Won kin no bredi no dey dull am
O wun emi na kin lo j'amala pekam

Ogologo
Ogo to le kongo
Ogologo
Ogo to le kongo

Ologo rainbow
Osha propro
Ogologo lyrical mafia emi ogbologbo

Ogologo
Mo n korin mo tun mo ijo jo
Ogologo
Mo mowo mo tun mo oju obo

Ogologo
Mo mo iwe mo tun mo Igbo we
Ogologo
Ori olori lo nlo eran Iya oshogbo

Lagbara fu ɾo ké lo gbé agbara le
Agbo zanku la wa ké lo bo agbara le
Iρhone x mas e ma lo jé oja bo le
Awon [C7]Omo wase?

Eleha to [C7]si sardine àwo ɾi àwo
O fẹ wá mí wálé kò wá bà mí là gbó
Je ka ɾí ɾa Later àbí ká pàdé lá gbó
Àwa má ɾí má kò ẹyin ká ɾí ká sho

Never broke again àwọn ìjọba ceecee
Chevrolet camaro ya tó infinity
Ara utility mi ò ní gungirity
Má tá fele fele Come My vicinity

Garri ó need ìpolówó
Àti mo pé ẹni Mission
Ọlopa mú ẹ ó ní kó má gbé e gba títí
Ọmọ àṣẹ kò sá tí de Station

Ogologo
Ogo to [C7]le kongo
Ogologo
Ogo to [C7]le kongo

Ologo ɾainbow
Osha propro (Osha pra pra)
Ogologo
Lyrical mafia ẹ mi ogbologbo

Ogologo
Mo n korin mo tun mo ijo jo
Ogologo
Mo mowo mo tun mo oju obo

Ogologo
Mo mo we mo tun mo Igbo wé
Ogologo
Ori olori lo nlo eran Iya oshogbo

Osha lè fo fún adìẹ
Osha lè do mummy [A]
Olosho tún lè sha Daddy ẹ
Bí Zlatan Sọ lè gbé body ẹ

A Sha lè fò fún adìẹ
Osha lè do mummy [A]
Olosho tún lè sha Daddy ẹ o
Bí Zlatan sọ lè gbé body ẹ

Ìtumò ìtumò yẹ ìtumò ye
Abu Abel ó bá má?
Alaye ṣe bí o kàwé sebi ó Mọ wé
Ó tún wá ɾí ìṣe láyé

Sọ ɾí pé oje lọ láyé
Lọ ɾa lappy kò wá hacker sì Malay
Arin giniginini arin gini
Arin ginini wó ọjà

Ilé mọ wo di ilé owó
Ọna mó gbá ọ'nà mọ gbá di ọ'nà ola
Àpótí mó fi joko àpótí ajé
Ìyẹn di àpótí alaje

Òkè àgbà ní mo gùn
òkè àgbà òkè àgbà ní mó gùn
Cblack
Marlians (Mafians)

Ogologo
Ogo to [C7]le kongo
Ogologo
Ogo to [C7]le kongo

Ologo ɾainbow
Osha prapra
Đăng nhập hoặc đăng ký để bình luận