Kabiesi, ka bi o o ma ma si
A se Iba fun o
Adakedajo, Olori Ogun Israeli
O ni toju wa
Iyin ye o o Jesu
Iyin ye Olorun yi o, Iyin ye
Jesu to fa wa yo ninu koto aiye
Iyin ye Olorun yi o, iyin ye
Ogo ye messiah yi o, ogo ye
Jesu to [C7]fa wa yo ninu koto [C7]aiye
Ogo ye messiah yi o, ogo ye
Ohun nikan loba to [C7]yo omo ɾe lofin
Ohun nikan loba to [C7]ta eje ɾe fun wa
Ohun nikan loba to [C7]ku fun gbogbo aiye o
Iyin ye Olorun yi o, iyin ye
Ohun lo ko wa yo
Ohun lo tu wa sile
Ohun lo gba wa la
Lati owo ota
Ni gba ti won [C7]kora jo
Ti won [C7]da ejo wa oo
Oba mimo fi agbara ɾe han larin won
Iyin ye Olorun yi o, Iyin ye
Iyin ye Olorun yi o, Iyin ye
Jesu to [C7]fa wa yo ninu koto [C7]aiye
Iyin ye Olorun yi o, iyin ye
Iyin ye Olorun yi o, Iyin ye
Iyin ye Olorun yi o, Iyin ye
Jesu to [C7]fa wa yo ninu koto [C7]aiye
Iyin ye Olorun yi o, iyin ye
Jesu ko seni ti a le fi o we
Ko seni ti o le da o duro
Eyin ni Balogun ogun ti ngbe [Am]Ija onija ki eru ba onija
Olubori Ajabori Olusegun Ajasegun
Akani eleru
Baba mi to [C7]to [C7]fara ti bi oke
Gbani gbani ti a nsaya
Iwo lope ye
Iwo ni iyin ye
Iyin ye Olorun yi oo, Iyin ye
Jesu ko seni ti a le fi o we
Ko seni ti o le da o duro
Eyin ni Balogun ogun ti ngbe [Am]Ija onija ki eru ba onija
Olubori Ajabori Olusegun Ajasegun
Akani eleru
Baba mi to [C7]to [C7]fara ti bi oke
Gbani gbani ti a nsaya
Iwo lope ye
Iwo ni iyin ye
Iyin ye Olorun yi o, iyin ye
Ohun lo ko wa yo
Ohun lo tu wa sile
Ohun lo gba wa la
Lati owo ota
Ni gba ti won [C7]kora jo
Ti won [C7]da ejo wa oo
Oba mimo fi agbara ɾe han larin won
Iyin ye Olorun yi o, Iyin ye
Iyin ye Olorun yi o, Iyin ye
Jesu to [C7]fa wa yo ninu koto [C7]aiye
Iyin ye Olorun yi o, iyin ye
Iyin ye Olorun yi o, Iyin ye
Iyin ye Olorun yi o, Iyin ye
Jesu to [C7]fa wa yo ninu koto [C7]aiye
Iyin ye Olorun yi o, iyin ye
Iyin ye Olorun yi o, Iyin ye
Iyin ye Olorun yi o, Iyin ye
Jesu to [C7]fa wa yo ninu koto [C7]aiye
Iyin ye Olorun yi o, iyin ye
Iyin ye Olorun yi o, Iyin ye
Iyin ye Olorun yi o, Iyin ye
Jesu to [C7]fa wa yo ninu koto [C7]aiye
Iyin ye Olorun yi o, iyin ye
Oba ogo, a se iba fun eh ooo
iyin ye olorun yi o Iyin ye
Gbani gbani lo jo ogun le
Iyin ye Olorun yi o, iyin ye
Abe [Am]tilu Kara bi ajere
Iyin ye Olorun yi o, iyin ye
Erujeje foba farao leti okun pupa
Iyin ye Olorun yi o, iyin ye
The Lord is worthy of praise
Iyin ye o jesu
Iyin ye Olorun yi o, iyin ye
Fenfe fenfe joro joro
Iyin ye Olorun yi o, iyin ye
Olorun ti oun je mimo
Ti oun mu mimo
Iyin ye Olorun yi o, iyin ye
Ti ongbe [Am]bi mimo
Kabiesi
Iyin ye Olorun yi o, iyin ye
Iyin ye o jesu yi
Iyin ye Olorun yi o, iyin ye
Jesu to [C7]fa wa yo ninu koto [C7]aiye
Iyin ye Olorun yi o, iyin ye
Jesu to [C7]fa wa yo ninu koto [C7]aiye
Iyin ye Olorun yi o, iyin ye