Uh uh
Eh
Eh
Oh oh oh
Oh oh
Oh oh ah ah
Gbekele
Ojo tipe to ti n reti iyanu
O ti gbiyanju Oti se'won to lese
Sugbon ma so ireti nu
ranti eleda re
Gbekele yi o gba o
Ojo tipe to ti n reti iyanu
O ti gbiyanju Oti se'won [C7]to [C7]lese
Sugbon [C7]ma so ireti nu
ranti eleda ɾe
Gbekele yi o gba o
Jesu n gbala Jesu n wo San
Iwo sa ti gbagbo
Gbekele ko ɾo mo
Yi o wa pelu ɾe
Jesu n gbala Jesu n wo san
Iwo sa ti gbagbo
Gbekele yi o gba o
Ah
Gbekele oh
Ah ah
Gbekele se
Uh uh uh uh uh uh uh
Yi o gba o
Omo igbagbo jowo teti ko gbo mi
Mase beru mase fo'ya duro do'luwa
Ko ma so hun to [C7]soro
Fun baba loke
Iwo sa ti ɾo Mo Jesu oooo
Lazaru oku ojo merin Jesu ji dide
Obinrin oni isun eje o fowo kan Jesu
Nipa igbagbo to [C7]ni ori iwosan gba
Ko ma so'hun to [C7]soro fun Jesu oooo
Jesu n gbala Jesu n wo San
Iwo sa ti gbagbo
Gbekele ko ɾo mo
Yi o wa pelu ɾe
Jesu n gbala Jesu n wo san
Iwo sa ti gbagbo
Gbekele yi o gba o
Jesu n gbala Jesu n wo San
Iwo sa ti gbagbo
Gbekele ko ɾo mo
Yi o wa pelu ɾe
Jesu n gbala Jesu n wo san
Iwo sa ti gbagbo
Gbekele yi o gba o
Jesu n gbala Jesu n wo San
Iwo sa ti gbagbo
Gbekele ko ɾo mo
Yi o wa pelu ɾe
Jesu n gbala Jesu n wo san
Iwo sa ti gbagbo
Gbekele yi o gba o
Gbekele yi o gba o