Ma wa f'owo la mofe mi la oniyan to ba ti Loire
Keyo o Kimi RI
Ma wa f'owo la mofe mi la oniyan to ba ti Loire
Keyo o Kimi RI
Emi omo Mukan Lakan
Emi omo jekan Jekan
Omo t'iya bi to Fi oja aran pan
Lai s'okun eran
Moyato s'awon [C7]omo po bi osan to [C7]jabo
Emi omo Mukan Lakan
Emi omo jekan Jekan
Omo t'iya bi to [C7]Fi oja aran pan Lai s'okun eran
Moyato [C7]s'awon [C7]omo po bi osan to [C7]jabo
Ma wa f'owo la mofe mi la
Emi omo Mukan Lakan
Ma wa f'owo la mofe mi la
Emi omo jekan Jekan
Ogbon [C7]ni mofimi Tayo Lo
Omo t'iya bi to [C7]Fi oja aran pan
Lai s'okun eran
Ogbon [C7]ni mofimi Tayo Lo
Moyato [C7]s'awon [C7]omo pO
Bi osan to [C7]jabo
Sho n be [Am]ni? Sho n mo mo ni?
Shey afishey ni? Abi Ogun ni?
Sho Ori ɾan ni sholoju ni?
Sho on'imu ni sho ngbo ɾun ni?
Sho oleti ni sho n gb'Oro ni ?
Sho olenu ni sho le soro ni?
Soro soke were
Morin pelu agbamu
Moderi nkan gbamu
Motir'Ire gbamu
Motir'Ayo gbamu
Mof'omo Tonidi to [C7]fine totun Lomu
Jesus K'Ore dasile
Mok'owo mok'Omo bante pelu Igbadi
Anawo aluwo
Agbawo agbawowo
Ogbeni iya babayin Eni duro
Hmmm Eni duro
Odo ate Lako'Iru Odo ate Lako'Iyo
Oh Y'all
Eyan gidi ni kobami yo
Bi owara ba pe'igba nigbo
Eyokan Lon [C7]ha Haha
Shogun laye ni ota eti ha
Ewe oriji L'oni kefori temi Jimi
Kede tun f'owo Jimi
Kede tun f'ola jinmi
Omo onidi nLa khefi gbogbo e Jinmi
Nopain lon [C7]soro awon [C7]eyan Jimi
Besi mi and [Bm]see the outcome
Besi mi and [Bm]see the outcome
Mapada sile Tori tie
Go back to [C7]the hood that I Came from
Mafi ye e Pomo Ogun to [C7]Yi Nimi pe mide ki SoMo Belgium
Efara bale kos'ofo
Ekawo sori erogo
Ada keso agbeje mowo
K'ara Malo paya yin TogoTogo
Efo de yato [C7]s'ewedu o
Emu gidi yato [C7]s'obu
Iwo nikan ko lodoti ju o
Situation [C7]Loso wa the Dj jentle
MiO gboran MiO gbadun o
Mio ni ɾespect motun buru o
Ibile ni mi ogbodo obey
Take it or leave it or fade away
Mo to [C7]so fun e ko dayan mo
Otun mo mi otun s'eyan mo
Orimi Losan o n shiranran
Tobarimi Loru waya were hnnnh
Oloun Oba Lonimi
Okanran gan denimi
Ijimere tunni mi
Obatala tunni mi
Arikutaku ni mi
Omo iya Shango ni mi
Eleguwa tun ni mi
Iya mi obimo Lemi Owe tun ni
P'eni bama b'esu jeun
Shibi e gan magun Debi
Emi Lomo Mukan Mukan
Jekan Jekan Lakan Lakañ
Eba kikan Obe [Am]kikan be [Am]aoku
Openi f'Oloun Oba Kan
(Alhamdulilah)
Odo ate Lako'Iru Odo ate Lako'Iyo
Oh Y'all
Eyan gidi ni kobami yo
Bi owara ba pe'igba nigbo Eyokan Lon [C7]ha
Haha
Shogun laye ni ota eti ha
Ewe oriji L'oni kefori temi Jimi
Kede tu tun f'owo Jimi
Kede tun f'ola jinmi
Omo onidi nLa khefi gbogbo e Jinmi
Nopain lon [C7]soro awon [C7]eyan Jimi
Emi ni emi ma ma ɾe o
Omo t'iya bi to [C7]Fi oja aran pan
Lai s'okun eran
Moyato [C7]s'awon [C7]omo pO
Bi osan to [C7]jabo
Emi omo Mukan Lakan
Emi omo jekan Jekan
Omo t'iya bi to [C7]F'oja aran pan
Lai s'okun eran
Moyato [C7]s'awon [C7]omo po bi osan to [C7]jabo
Emi omo Mukan Lakan
Emi omo jekan Jekan
Omo t'iya bi to [C7]F'oja aran pan
Lai s'okun eran
Moyato [C7]s'awon [C7]omo pO bi osan to [C7]jabo